Folashade Adefisayo
Ìrísí
Folashade Adefisayo | |
---|---|
Lagos State Ministry of Education | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2019 | |
Gómìnà | Babajide Sanwo-Olu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Education |
Folashade Adefisayo jẹ́ olùkọ́ àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni Kọmíṣọ́nà fún Ẹ̀ka ìpínlè Ẹ̀kọ́ tí ó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́.[2][3][4]
Ẹ̀tò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó lọ ilé ìwé Yunifásítì ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ bachelor nínú ìmò Zoology.[1] Lẹ́yìn náà, ó te ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ìpínlè Èkó níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ Master degree nínú ìmọ̀ ìdarí òwò àti àmì ẹyẹ Master degree nínú ìmò Èkọ́ ní Yunifásitì ti Nottingham.[1]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Folashade sí ìlú Èkó, tí ó sì dàgbà sí ìlú Ibadan, ní Nàìjíríà. Òn sì ni ọmọbìnrin tó dàgbà jù láàrin àwọn ẹ̀bí márùn-ún rè, bẹ́ẹ̀ sì ni ó fẹ́ràn láti máa kàwé àti rínrin ìrìn-àjò.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 "Edugist Presents a Seasoned Academic, Folasade Adefisayo, to Proffer Ways to Revive and Strengthen Public Education in Nigeria". Edugist (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-13. Retrieved 2020-11-11.
- ↑ "Lagos orders resumption of remaining classes in public, private schools". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-13. Archived from the original on 2020-10-20. Retrieved 2020-11-11.
- ↑ "Lagos is prepared for new normal in education —Adefisayo -". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-06. Retrieved 2020-11-11.
- ↑ "Folashade Adefisayo Archives | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-11.
- ↑ "My dream is to go and watch athletes at the Olympics –Adefisayo". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-11.