Folashodun Adebisi Shonubi
Ìrísí
Folashodun Adebisi Shonubi (tí wọ́n bí lọ́jọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1962) [1] [2]jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria àti Gómìnà-fìdíhẹ Ilé-ìfowópamọ́-àgbà, the (Central Bank of Nigeria) tí Ààrẹ Bọlá Ahmed Tinubu yàn lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 2023 láti rọ́pò Gómìnà-àná Ilé-ìfowópamọ́-àgbà, Godwin Emefiele tí wọn dá dúró lẹ́nu iṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ nítorí àwọn ẹsùn àwọn ìwà àjẹbánu kan.[3] [4] [5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Why Tinubu suspended Emefiele as CBN gov". The Nation Newspaper. 2023-06-10. Retrieved 2023-06-10.
- ↑ "Meet acting CBN Governor, Folashodun Shonubi". Vanguard News. 2023-06-09. Retrieved 2023-06-10.
- ↑ "CLOSE-UP: Folashodun Adebisi Shonubi, engineer, IT expert, banker -- and acting CBN governor". TheCable. 2023-06-09. Retrieved 2023-06-10.
- ↑ Egobiambu, Emmanuel (2023-06-09). "President Tinubu Suspends Emefiele As CBN Governor". Channels Television. Retrieved 2023-06-10.
- ↑ Bankole, Idowu (2023-06-10). "Tinubu suspends CBN Gov, Emefiele". Vanguard News. Retrieved 2023-06-10.