Jump to content

Gògóńgò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Throat
The human throat.
X-ray showing the throat, seen as a dark band to the front of the spine.
Details
Identifiers
Latingula
jugulum
FMA228738
Anatomical terminology

Gògóńgò ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹ́yà ara ìfọ̀ tí ó wà ní iwájú ọrùn gbogbo ẹranko elégungun.

Gògóńgò ni ó ń ṣàkóso bí ohun jíjẹ àti mímu kò ṣe ní gba òdì nípa ṣíṣètò ìyàtọ̀ láàrin ònfà ọ̀fun, ohùn àti tááná tí ó gbé èémí jáde nígbà tí a bá ń jẹun lọ́wọ́. Gògóńgò tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí náà ni ó tún gbé ọ̀pá ẹ̀jẹ̀ (blood vessel) oríṣríṣi. Gògóńgò ẹranko elégungun ní oríṣríṣi eegun méjì tí a mọ̀ sí (egungun hyoid) àti (clavicle).[1] Ẹ̀wẹ̀, gògóńgò tún ń ṣíṣẹ́ pẹ̀lú ẹnu, etí,imú àti púpọ̀ nínú àwọn ẹ̀yà ara gbogbo.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "throat" at Dorland's Medical Dictionary
  2. "Throat anatomy and physiology". Children's Hospital of Philadelphia. Retrieved 7 August15.  Check date values in: |access-date= (help)