Gbenga Adébóyè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Gbenga Adeboye Abefe Funwontan
Ọjọ́ìbíSeptember 30, 1959
Osun State, Nigeria
AláìsíApril 30, 2003
Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànFunwontan Oduology
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Comedian
Olólùfẹ́Omolara Gbenga Adeboye[1]
Parent(s)Rebecca Tinuola Adeboye (mother)[2]
Àwọn olùbátanDamilola Gbenga Adeboye (Daughter)[3]

Gbénga Adébóyè (1959 – Kẹrin 2003) jẹ́ akọrin, apanilẹ́rìín, olótùú ètò orí rèdíò àti olùdarí ayẹyẹ.

Ibẹ̀rẹ̀ aye rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Elijah Olúwágbémiga Adébóyè ni wọ́n bí ní ọgbọ̀n Ọjọ́ oṣù Késàn ọdún 1959 (30,9,1959), ní ìlú Ọdẹòmu ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ní gúsù ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà[4]

Ìgbòkè-gbodò iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ ògbóntagì sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Orí rédíò ní Ipinlẹ̀ Èkó ní ibẹ̀rẹ̀ ọdún 1980, ní bi tí ó ti gba ìnagijẹ rẹ̀ 'Fúnwọntán Oduọ́lọ́jì' . Gbajúgbajà òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ìdòwú Philip tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí 'Ìyá Rainbow' ṣàpèjúwe Gbenga gẹ́gẹ́ bí adẹ́rìín-pòṣónú àti aláwàdà tí ó ma ń tọrẹ àtinúwá fẹ́ni tó bá ni lo ìrànlọ́wọ́. Nigba tí ó ń sọ bí Gbenga ṣe fun òun ní ọkọ ayọ́kẹ́lẹ́ àkọ́kọ́ tí òun kọ́kọ́ ní láyé òun. Wọ́n tu ṣàpèjúwe olóògbé náà gẹ́gẹ́ bí òntajà àti aláfihàn fàbú lọ́nà ìbílẹ̀ ṣáájú kí ó tó papò da látàrí àìsàn tí ó níṣe pẹ̀lú kídìnrín (kidney related diseases) ,ní ọjọ́ Kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́rin, ọdún 203.

Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "I Kill Ram Yearly For My Husbands Remembrance - ...Regret Ever Marrying From Adeboyes Family - Lar". modernghana.com. Retrieved 11 February 2015. 
  2. "Gbenga Adeboye's Mother For Burial Sept 13". thenigerianvoice.com. Retrieved 11 February 2015. 
  3. "Dad was a car freak — Gbenga Adeboye’s daughter". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 29 January 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  4. "Find Gbenga Adeboye's songs, tracks, and other music". Last.fm. 2018-10-10. Retrieved 2019-08-16.