Jump to content

Gregory Ojefua

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gregory Ojefua
Ọjọ́ìbíIgueben, Edo State, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaAdekunle Ajasin University
Iṣẹ́actor, model, and television presenter
Ìgbà iṣẹ́2014–present
Notable workGold Statue, It's Her Day, Dwindle (film), Òlòtūré

Gregory Ojefua (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù keje) tí a tún mọ̀ sí Greg tàbí Teddy Bear jẹ́ ọ̀ṣèré láti ìlú Naijiria, àti ólùsọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòràn

Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gregory Ojefua jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Igueben, ní ipinle Edo ní orile- orílé-ede Naijiria . Ó parí ẹ̀kọ́ alákọbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlú rẹ̀ kó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Adekunle Ajasin ni Ìpínlẹ̀ Ondo tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣòwò àti Ìṣàkóso ìṣòwò .

Gregory Ojefua bẹ̀rẹ̀ ìṣeré láti kékeré kí ó tó mú ní ìṣẹ́ ní ọdún 2015 látàrí jíjáde rẹ̀ nínu àwọn fíìmù àgbéléwò oríṣiríṣi.

Ojefua tí kó oríṣiríṣi ipa nínu àwọn fíìmù oríṣiríṣi.

Òkìkí rẹ̀ tàn látàrí ipa Odumegwu Ojukwu tó kó nínu fíìmù "The Encounter"

Àwọn àmì ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gregory Ojefua jẹ́ àbá fún Àmì ẹ̀yẹ Òṣeré tí ó dára jù lọ nínu Ere-idaraya ni Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA) ní ọdún 2017, Ó gbà àmì ẹ̀yẹ ọ̀ṣèré tí ó dára jù lọ ní Africa International Film Festival (AFRIFF) ní ọdún 2023.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]