Jump to content

Halle (akorin)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Halle
Orúkọ àbísọHalle Grace Ihmordu
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiHalle
Ọjọ́ìbíÌpínlẹ̀ Edo, Nàìjíríà
Irú orinOrin Afro pop music, Reggae, dancehall
Occupation(s)Akọrin
Years active2004–present
LabelsN3rd Records
theMedia 360 Company
Associated acts
Websitehallemordu.com

Halle (orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Halle Grace Ihmordu; a bi ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù Kejìlá) jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin, àti oníjó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ fún N3rd Records.

Ní ọdún 2008, ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú fíìmù Relentless (2008–2009), wọ́n padà ṣe àgbéjáde fíìmù náà ní BFI London Film Festival ní ọdún 2010.[1] Èyí ni fíìmù àkọ́kọ́ tí ó ti ṣeré; àwọn òṣèré tí ó tún wà nínú fíìmù náà ni Gideon Okeke, Nneka Egbuna, Jimmy Jean-Louis àti Tope Oshin Ogun.

Kí ó tó di òṣèrébìnrin, Halle, ma ń jó, ó ti jó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ìjọ́, ó sì jáwé olúborí ní àwọn ìdíje bi ìdíje Channel O Dance Africa, àti the last female standing ní Maltina Dance Hall (ọdún 2008). Ní ọdún 2012, ó ṣe àgbéjáde orin àkọ́kọ́ rẹ̀, Falling in Love, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì gba ti orin náà.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Akideinde, Oye (October 6, 2010). "360Trailers: "Relentless" starring Jimmy Jean-Louis, Gideon Okeke, Halle Mordu & Nneka Egbuna". 360Nobs.com. Archived from the original on July 14, 2018. Retrieved October 4, 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)