Haruna Ishola
Ìrísí
Hárúnà Bello Ìṣọ̀lá (1919 - 9 November, 1983) jẹ́ gbajúgbajà Olórin Àpàlà ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1]
Iṣẹ́ orin kíkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìlú Ibadan ni wọ́n bí wọn sí, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]
Àwo-orin akọ́kọ́ tí Ishola ṣe jáde ní ọdún 1948. Ní ọdún 1955, wọ́n tún orin náà gbà sílẹ̀ lẹ́yìn tí ọba Adeboye wàjà nínú ìjàmbá ọkọ̀ òfurufú kan.[3] Orin tí wọ́n tún kọ yìí mú wọn gbajúmọ si.[4] Haruna Ishola bẹ̀rẹ̀ sí kọ orin àpàlà, tí ó si tún ń gba á sílẹ̀ ní ọdún 1955, èyí sì sọ ọ́ di olókìkí si. Nínú orin rẹ, ó máa ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn òwe Yorùbá àti ẹsẹ Kuraani. Ni ọdún 1950, o fi Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ kun orin rẹ̀, ó sì kọ orin "Punctuality is the Soul of Business" fún Decca Records.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Afropop Worldwide: Haruna Ishola Archived 2006-02-11 at the Wayback Machine.
- ↑ Colin Larkin, ed (1992). The Guinness Encyclopedia of Popular Music (First ed.). Guinness Publishing. p. 1237. ISBN 0-85112-939-0.
- ↑ 3.0 3.1 Àdàkọ:Cite videoÀdàkọ:Cbignore
- ↑ "O N I G E G E W U R A: Death of a Musical Partnership: The Story of Haruna Ishola and Nurudeen Alowonle". Onigegewura.blogspot.com. 6 October 2017. Retrieved 16 September 2021.