Hassan Usman Sokodabo
Ìrísí
Hassan Usman Sokodabo | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria from Federal Capital Territory | |
Constituency | Abaji/Gwagwalada/Kuje/Kwali |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1969 |
Aráàlú | Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
Occupation | Politician |
Hassan Usman Sokodabo je olóṣèlú ọmọ Nàìjíríà . O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti o nsoju Abaji / Gwagwalada / Kuje / Kwali ni Ile ìgbìmò aṣòfin. [1] [2]
Igbesi aye ibẹrẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún 1969 ni wón bi Hassan Usman Sokodabo [1] [2]
Ìrìnàjò òṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2022 ó dije dùn ipò nínú ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) nínú ìdíje àlábenu títí ẹgbẹ ti òsì tẹ síwájú gẹgẹbi oludije tí ẹgbẹ fà kalẹ nínú ètò ìdìbò Gbogbogbòò ni ọdun 2023 tí osi ja èwe olubori gẹgẹbi aṣofin àgbà fún ìgbà kejì. Sokodabo to fi ìgbà kan jẹ Komisona olú ìlú Abuja ni Federal Character Commission. Pẹlu àjọṣe pò àwọn aṣofin ọtí ṣe atokun àbá do fín márùn-ún.[3][4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 https://constrack.ng/legislator_details?id=359 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name ":0" defined multiple times with different content - ↑ 2.0 2.1 https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/hassan-sokodabo-usman Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name ":1" defined multiple times with different content - ↑ https://dailyasset.ng/sokodabo-wins-pdp-abuja-south-house-of-representatives-ticket/
- ↑ https://orderpaper.ng/new/?p=2961