Herbert Macaulay

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Herbert Macaulay.jpg

Herbert Samuel Heelas Macaulay (November 14, 1864May 7, 1946) je oloselu omo ile Naijiria.

Omo omo Bishop Samuel Ajayi Crowther ni. A bí i ní 1864. Ó gboyè Enjiníà ní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Òun ni omo Nigeria àkókó tó kókó ní káà. Ó dá egbé òsèlú sílè ní 1923. Ó kú ní 1946 níbi ti ó ti n se kànpéè.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]