Idibo ile igbimo asofin ipinle Eko lodun 2015
Idibo ile igbimo asofin ipinle Eko lodun 2015 waye ni ojo kokanla osu kerin odun 2015 lati yan awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko ni Naijiria. Gbogbo ogoji ijoko lo wa fun idibo ni ile igbimo asofin ipinle Eko. APC gba aga mejilelogbon, nigba ti PDP gba aga mejo.
Nigba ti sisi ile igbimo asofin ipinle kejo ti waye, Mudashiru Obasa (APC-Agege I) ni won yan gege bi olori ile igbimo asofin nigba ti Wasiu Sanni (APC-Lagos Island I) ati Agunbiade Sanai (APC-Ikorodu I) di igbakeji olori ile igbimo asofin ati ile igbimo asofin. Olori, lẹsẹsẹ.
Esi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Badagry I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Layode Olanrewaju lo jawe olubori ninu idibo naa.
Apapa II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Jimoh Olumuyiwa lo jawe olubori ninu idibo naa.
Apapa I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Lawal Mojisola Lasbat lo jawe olubori ninu idibo naa.
Alimosho I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Adebisi Yusuff lo jawe olubori ninu idibo naa.
Alimosho II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Omo Egbe APC Oduntan Omotayo ni o Jawe Olubori leyin idibo na
Agege II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oluyinka Ogundimu to jẹ oludije egbe APC lo jawe olubori ninu idibo naa.
Agege I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Mudashiru Obasa lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikeja I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Folajimi Mohammed lo jawe olubori ninu idibo naa.
Kosofe II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Tunde Braimoh lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikeja II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Adedamola Kasumu lo jawe olubori ninu idibo naa.
Somolu II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Abiru Rotimi Lateef lo jawe olubori ninu idibo naa.
Badagry II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Setonji David lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Island II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Giwa Sakirudeen lo jawe olubori ninu idibo naa.
Epe I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Tobun Abiodun lo jawe olubori ninu idibo naa.
Epe II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Segun Olulade lo jawe olubori ninu idibo naa.
Eti-Osa I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Alimi Kazeem Ademọla tó jẹ́ olùdíje nínú ẹgbẹ́ òṣèlú APC ló jáwé olúborí ninu idibo na.
Eti-Osa II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Yisawu Olusegun Gbolahan lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ibeju/Lekki I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Mojeed Fatai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ibeju/Lekki II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Kazeem Raheem Adewale lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ifako/Ijaye I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Dayo Fafunmi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ifako/Ijaye II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Makinde Rasheed Lanre lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikorodu I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Agunbiade Sanai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikorodu II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Solaja-Saka Nurudeen lo gba ibo naa.
Kosofe I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Osinowo Sikiru lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Island I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Wasiu Sanni lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Mainland I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Adekanye Oladele lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Mainland II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Ọṣun Moshood lo jawe olubori ninu idibo naa.
Mushin I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Tejuoso Funmilayo lo jawe olubori ninu idibo naa.
Mushin II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Olayiwola Olawale lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ojo II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Lanre Ogunyemi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Somolu I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC, Rotimi Olowo lo jawe olubori ninu idibo naa.
Surulere I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe APC Desmond Elliot jawe olubori ninu idibo naa.
Surulere II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Mosunmola Sangodara-Rotimi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ajeromi/Ifelodun II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Oluwa Olatunji Fatai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ojo I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Olusegun Victor Akande lo jawe olubori ninu idibo naa.
Oshodi/Isolo II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Emeka Odimogu to jẹ oludije ninu egbe PDP lo jawe olubori ninu idibo naa.
Oshodi/Isolo II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Shokunle Hakeem lo jawe olubori ninu idibo naa.
Amuwo/Odofin II
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Hakeem Bello lo jawe olubori ninu idibo naa.
Amuwo/Odofin I
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oludije egbe PDP Dipo Olorunrinu lo gba ibo naa.
Oludije egbe PDP Famakinwa Adedayo Olufemi lo jawe olubori ninu idibo naa.