Mudashiru Ọbasá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Right Honourable
Mudashiru Obasa
Mudashiru Obasa.jpg
Speaker of the 8th Lagos State House of Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2015
Asíwájú Adeyemi Ikuforiji
Constituency Lagos, Agege Constituency I
Member of the Lagos State House of Assembly
Lórí àga
2011–2015
Member of the Lagos State House of Assembly
Lórí àga
2007–2011
Personal details
Ọjọ́ìbí Oṣù Kọkànlá 11, 1972 (1972-11-11) (ọmọ ọdún 47)
Nationality Nigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlu All Progressive Congress (APC)
Relations Married
Residence Lagos
Alma mater LASU
Occupation Legislature
Profession Legal Practitioner

Mudashiru Àjàyí Ọbasá jẹ́ agbẹjọ́rò, olóṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress ilẹ̀ Nàìjíríà kan. Òun tún ni ó jẹ́ agbẹnusọ fún ilé ìgbìmọ̀ Aṣojúsòfin ìpínlẹ̀ Èkó lọ́wọ́lọ́wọ́.[1]

Ibẹ̀rẹ̀ aye rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abbí ilù Agege, ní ìpínlẹ̀ Èkó ní apa gúsù ìwọ̀ Olorun ilẹ̀ Nàìjíríà. [2]

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ St Thomas Acquinas ní Sùúrù-lérè, ṣáájú kí ó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ girama Archbishop Aggey Memorial, ní ìlú Mushin, ní agbègbè Ìlasa-màjà, ní ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gba ìwé ẹ̀rí ìdánwò àpapọ̀ Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ (WAEC). [3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀òfinIlé-Ẹ̀kọ́ Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2006. [4]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olóṣèlú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 1999, Mudashiru díje dupò sí ipò àga ijọba ìbílẹ̀ Agege lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy bori ó sì borí, léyìí tí ó ṣiṣẹ́ nibẹ̀ láàrín ọdún 1999 sí 2002. [5]

Ẹ̀wẹ̀, ó ran díje dupò sí Ilé ìgbìmọ̀ aṣojúṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó ní ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ Agége ní ọdún 2019, tí ó sì tún jáwé olúborí nínú ìdìbò naa, tí ó sì sọ́ di agbẹnusọ́ fun Ilé ìgbìmọ̀ náà ní Ipinlẹ̀ Ẹ̀kó. [6]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]