Lagos State House of Assembly
Jump to navigation
Jump to search
Lagos State House of Assembly | |
---|---|
![]() | |
Aṣolórí | |
Olórí | Mubashiru Obasa, APC |
Ìpele | |
Ìjọ́kòó | Ogójì |
Length of term | Ọdún mẹ́rin |
Meeting place | |
Ìlú Èkó |
Lagos State House of Assembly jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó wà ní ilé ìjọba Ìlú Èkó ní Alausa, Ikeja. ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso ẹgbẹ́ òṣèlu All Progressives Congress tí ó ń ṣe ìjọba Ìlú Èkó lọ́wọ́ lọ́wọ́. Ilé ìgbìmọ̀ méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló ti wà, àkọ́kọ́ wáyé ní oṣù kẹwá ọdún 1979 tí èyí tó ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ sì bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 2011.[1][2] Ogójì aṣojú ni ó wà ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, méjì láti ìjọba ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan ní Ìlú Èkó.
Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lọ́wọ́ lọ́wọ́ ni Rt. Hon Mubashiru Obasa tí ó sì jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí wọ́n maa yàn sí ipò yìí lẹ́ẹ̀mẹta.[2][3]
Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "The Lagos State House of Assembly". Library of Congress Africa Pamphlet Collection - Flickr. Retrieved 2014-05-12. More than one of
|accessdate=
and|access-date=
specified (help) - ↑ 2.0 2.1 Ikuforiji, Adeyemi. "Lagos State House of Assembly".
- ↑ "Lagos State House of Assembly".