Ilojo Bar
Ìrísí
Ilojo Bar, tí wọ́n tún ń pè ní Ilé Ọláìyá tàbí Casa da Fernández jẹ́ ilé ìṣẹ̀ǹbáyé tí wọ́n kọ́ bí ti àwọn Brazil tí ó wà ní Tinubu Square, Lagos Island, Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . [1] [2]
Orúkọ "Ilojo Bar"
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́yìn tí wọ́n tá ilé náà fún Alfred Omolona ní ọdún 1933, o yí orúkọ rẹ dà sí “Ilojo" èyí tí ó jẹ́ orúkọ ìlú rẹ̀ “Ilojo" ní Ìjẹ̀sà Ìṣù ni Ipinle Ekiti. [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Hakeem B. Harunah (2000). Nigeria's defunct slave ports: their cultural legacies and touristic value. First Academic Publishers. ISBN 978-978-34902-3-9. https://books.google.com/books?id=I8a4AAAAIAAJ.
- ↑ Edvige Jean-François. "Lagos' Afro-Brazilian architecture faces down the bulldozers". Cable News Network. http://edition.cnn.com/2017/07/19/architecture/nigeria-afro-brazilian-architecture/index.html.
- ↑ "A Tragedy of Confusing Interests" (in en-US). ktravula - a travelogue!. 2016-10-02. Archived from the original on 2021-12-11. https://web.archive.org/web/20211211223512/http://www.ktravula.com/2016/10/a-tragedy-of-confusing-interests/.