Nọ́mbà odidi
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Integer)
Nomba odidi (integer) je gbogbo awon nọ́mbà àdábáyé alapaotun {1, 2, 3,...} ati ti awon alapaosi won (−1, −2, −3, ...) pelu nomba òdo. Ami ti a fi n tokasi akojopo awon nomba odidi ni Z (tabi , tabi Unicode ℤ) ti o duro fun Zahlen (ti o tumosi nomba ni ede Germani)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |