Jump to content

Nọ́mbà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Awon nómbà

Àdàkọ:Nọ́mbà Nọ́mbà jẹ́ ohun afòyemò tó dúró fún iye tàbí ìwòn. Àmì-ìsojú fún nọ́mbà ní àn pé nì àmìnọ́mbà (numeral). Nì èdè ojojúmọ́, à n lo àwọn àmìnọ́mbà bí àkólé (fún àpẹrẹ nọ́mbà tẹlífònù, nọ́mbà ilé). Nínú ìmọ̀ ìṣirò ìtumò nọ́mbà tí s'àkomọ̀ àwọn nọ́mbà afóyemọ̀ bí idà (fraction), nọ́mbà apáòsì (negative), tíkòníònkà (transcendental) àti nọ́mbà tósòro (complex).

Àwọn ònà ìṣèṣirò nọ́mbà bí àropò, ìyokúrò, ìsodípúpò, àti ìṣepínpín ní a n sewadi wón nínú ẹ̀ka ìmọ̀ ìṣirò tí a mò sí aljebra afòyemọ̀ (abstract algebra), níbití a tí n sewadi àwọn ònà nọ́mbà afóyemọ̀ bí ẹgbẹ́ (group), òrùka (ring) àti pápá (field).


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]