Jump to content

Nọ́mbà áljẹ́brà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Algebraic number)
Nọ́mbà áljẹ́brà

Ninu mathematiiki, nomba aljebra je nomba tosoro kan to je wewe polynomial tikoje-odo ni oniyekiye eyo kan pelu oniipin (tabi lonibamu, odidi) afisodipupo. Awon nomba bi ti won ki se ti aljebra ni won so pe won je transcendental; Bi gbogbo won nomba gidi ni won je transcendental.

  • Àwọn nọ́mbà gidi, tí wọ́n jẹ́ gbígbékàlẹ̀ bíi ìpín nọ́mbà odidi méjì a àti b, tí b kò dọ́gba mọ́ òdo, nitelorun ìtumọ̀ ọkè nítorí ni wẹ́wẹ́ .[1]
  • Àwọn nọ́mbà àti jẹ́ ti áljẹ́brà nítorípé àwọn ni wẹ́wẹ́ àwọn polynomials àti , nitelentele.
  • Ipin oniwura je ti aljebra nitoripe o je wewe kan polynomial .
  • Awon nomba kiko (those that, starting with a unit, can be constructed with straightedge and compass, e.g. the square root of 2) je ti aljebra.
  • Awon quadratic surd (awon wewe quadratic polynomial pelu awon odidi afisodipupo , , ati ) je nomba onialjebra. Ti quadratic polynomial ba je monic nigbana awon wewe je quadratic integer.
  • Awon nomba odidi Gauss: awon nomba tosoro nibi ti ati ati je odidi na tun je quadratic integers.

Awon ini nomba aljebra

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Algebraic numbers coloured by degree.
  • Akojopo awon nomba aljebra je siseeka (enumerable).[3]
  • Bi be, akojopo awon nomba aljebra ni iwon Lebesgue odo (gege bi akojopoabe fun awon nomba tosoro)



  1. Some of the following examples come from Hardy and Wright 1972:159-160 and pp. 178-179
  2. Also Liouville's theorem can be used to "produce as many examples of transcendentals numbers as we please," cf Hardy and Wright p. 161ff
  3. Hardy and Wright 1972:160