Nọ́mbà àdábáyé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Àwọn nọ́mbà nínú ìmọ̀ mathematiki
Basic
\mathbb{N}\sub\mathbb{Z}\sub\mathbb{Q}\sub\mathbb{R}\sub\mathbb{C}

Nọ́mbà àdábáyé \mathbb{N}
Nọ́mbà alòdì
Nọ́mbà odidi \mathbb{Z}
Nọ́mbà oníìpín \mathbb{Q}
Nọ́mbà aláìníìpín
Nọ́mbà gidi \mathbb{R}
Nọ́mbà tíkòsí \mathbb{I}
Nọ́mbà tóṣòro \mathbb{C}
Nomba aljebra \mathbb{A}
Nọ́mbà tíkòlónkà

Complex extensions

Quaternions \mathbb{H}
Octonions \mathbb{O}
Sedenions \mathbb{S}
Cayley-Dickson construction
Split-complex numbers \mathbb{R}^{1,1}
Bicomplex numbers
Biquaternions
Coquaternions
Tessarines
Hypercomplex numbers

Other extensions

Musean hypernumbers
Superreal numbers
Hyperreal numbers
Surreal numbers
Dual numbers
Transfinite numbers

Other

Nominal numbers
Serial numbers
Ordinal numbers
Cardinal numbers
Nomba akoko
p-adic numbers
Constructible numbers
Computable numbers
Integer sequences
Mathematical constants
Large numbers
π = 3.141592654…
e = 2.718281828…
i (Imaginary unit) i^2 = -1
∞ (infinity)

This box: view  talk  edit

Nínú mathematiki, àwon nọ́mbà àdábáyé, tàbí nọ́mbà àdábá (Natural number) lé jé òkan nínú àkójopò {1, 2, 3,...} (èyun nọ́mbà odidi rere) tàbí òkan nínú àkójopò {0, 1, 2, 3, ...} (èyun gbogbo nọ́mbà tí kí se tí òdì).

A n ló nọ́mbà àdàbà fún kíkà ("Ọsàn mefa lowa ninu apẹ̀rè yị); bé ni á sí tún n ló won fún sisé ètò elésèsè ("Ipo keji ni Bùkọ́lá mu ninu ìdíje sàyẹ̀nsì odun yi").