Irène Tassembédo
Irène Tassembédo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹjọ 1957 |
Orílẹ̀-èdè | Burkina Faso |
Iṣẹ́ | Osere |
Irène Tassembédo (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kejo odun 1956) je onijo, akorin ati osere ti o wa lati orile ede Bùrkínà Fasò.[1]
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O ko ijo ibile titi Ouagadougou, lehin na o ko ijo imusin titi ile Europe, lehin Germaine Acogny, ni ile iwe Mudra Afrique, ti Maurice Bejart da sile ni Dakar[2][3] bbnxnxxmxnmxmmxmx,mxm
Lehin idanileko yi, o ko lo si ilu Europe gegebi onijo, ni awon odun ibere ti 1980,. O man lo si ilu Burkina Faso dada, ati pe o ti se orisisi ikose ni orile ede Orílẹ̀-èdè Ìṣọ̀kan àwọn Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà ati ni Europe. Ni odun 1988 o da Compagnie Ébène ni ilu Parisi, eleyi ni o fi se irin ajo lo si ilu orisirisi lati fi ise e gege bi olorin fi han si awon eyan. O sumo, o si tun ririn ajo pelu egbe Fusion ni odun 1988, ni odun 1989 o rin irin ajo pelu egbe Diminoïda. O ko ipa ninu ipade Caravane d'Afrique Francophone ti o waye ni ilu Paris, ni odun 1991. O bere Yenenga ni ilu Paris, ni osu kewa odun 1992[4] bbbbbb
Ni odun 1993, ohun ati egbe e ririn ajo wa si ipele akoko titi aworan ile Áfríkà ati idani laraya ti o waaye ni ilu Abidjan. O di gbajumo won si yan fun ijo ti o ma n waye ni ododun meji ti ti Lyon, ni odun 1994, okiki re gegebi akorin ati oni ijo tan kakiri. Ni odun 1998 o da Ebène ni Paris. O tun sise pelu ile abinibi e, lehin igba ti won da ajo onijo ballet titi Burkina Faso kale. Gege bi Irene Tassembo se so:"ki oto di igba yen, awon egbe ibile nikan ni o wa. A ko awon onijo lati origun Burkina, gbogbo won ko ijo ti won mo tele."[5]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Burkina Faso: Samira Sawadogo, actrice et businesswoman | Africa Top Success". www.africatopsuccess.com (in Èdè Faransé). Archived from the original on 2019-03-21. Retrieved 2017-11-08.
- ↑ "Irène Tassembedo, "inclassable" chorégraphe" (in fr). Le Monde.fr. 2001-09-15. ISSN 1950-6244. http://www.lemonde.fr/archives/article/2001/09/15/irene-tassembedo-inclassable-choregraphe_222086_1819218.html.
- ↑ "La Danseuse d'ébène" (in fr). Le Monde.fr. 2002-10-19. ISSN 1950-6244. http://www.lemonde.fr/archives/article/2002/10/19/la-danseuse-d-ebene_4249759_1819218.html.
- ↑ "DANSE Cinquante-six compagnies à la Biennale de Lyon Le grand écart des Africains de France" (in fr). Le Monde.fr. 1994-10-01. ISSN 1950-6244. http://www.lemonde.fr/archives/article/1994/10/01/danse-cinquante-six-compagnies-a-la-biennale-de-lyon-le-grand-ecart-des-africains-de-france_3853940_1819218.html.
- ↑ "Les noces d'Eschyle, de la France et de l'Afrique à Ouagadougou" (in fr). Le Monde.fr. 2000-01-16. ISSN 1950-6244. http://www.lemonde.fr/archives/article/2000/01/16/les-noces-d-eschyle-de-la-france-et-de-l-afrique-a-ouagadougou_3590858_1819218.html.