Ishaku Abbo
Ìrísí
Ishaku Abbo | |
---|---|
Sénátọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 June 2019 | |
Asíwájú | Binta Masi Garba |
Constituency | Adamawa North |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ishaku Elisha Abbo |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress APC |
Profession | Politician |
Nickname(s) | SIA |
Ishaku Elisha Abbo (tí a bí ní Mubi North, Nàìjíríà) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni Sénátọ̀ tí ó ń ṣe aṣojú àgbègbè Adamawa North Senatorial District ní Ìpínlẹ̀ Adamawa.[2][3] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress (APC) lọ́wọ́ lọ́wọ́.[4]
Ipa rẹ̀ nínú òsèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 2019, wọ́n yan Abbo gẹ́gẹ́ bi Sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè apá àríwá Adamawa, iye àwọn tí ó dìbò fun tó 79,337.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Feminist forum berates Remi Tinubu over alleged comments on Abbo". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-11. Archived from the original on 2022-02-21. Retrieved 2022-02-21.
- ↑ "Northern Nigeria’s only female senator loses seat to newcomer". The Punch.
- ↑ Garba, Tom. "Senator/Reps of Northern Adamawa zone have lost out to PDP". Nigeria Tribune. Archived from the original on 2 March 2019. Retrieved 25 February 2019.
- ↑ "Senator Elisha Ishaku Abbo dumps PDP for APC". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-25. Retrieved 2020-12-06.