Jacob Zuma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
His Excellency

Jacob Zuma
Jacob G. Zuma - World Economic Forum Annual Meeting Davos 2010.jpg
President of South Africa
Assumed office
9 May 2009
Deputy Kgalema Motlanthe
Preceded by Kgalema Motlanthe
President of the African National Congress
Assumed office
18 December 2007
Deputy Kgalema Motlanthe
Preceded by Thabo Mbeki
Member of Parliament
In office
1999–2005
Deputy President of South Africa
In office
14 June 1999 – 14 June 2005
President Thabo Mbeki
Preceded by Thabo Mbeki
Succeeded by Phumzile Mlambo-Ngcuka
Personal details
Born Jacob Gedleyihlekisa Zuma
12 Oṣù Kẹrin 1942 (1942-04-12) (ọmọ ọdún 75)
Inkandla, South Africa
Political party African National Congress (1959–present)
Other political
affiliations
Communist Party (1963–present)
Spouse(s) Gertrude Sizakele Khumalo (1973–present)
Kate Zuma (1976–2000)[1]
Nkosazana Dlamini (1982–1998)
Nompumelelo Ntuli (2008 – present)
Children 18

Jacob Zuma jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà tẹ́lẹ́.[2][3][4] Ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé African National Congress (ANC) ní Guusu Afrika.[5] Olóyè ni ó jé ní àárín àwọn Zulu. Ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bí ọmọ méjì fún un. 1943 ni wọ́n bí Jacob Zuma. Ìyàwó rẹ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ ní jẹ́ Kate pa ara rẹ̀ ní ọdúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwọn ti ṣe fún ọfún mẹ́rìnlélógún kò rọgbọ. Ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní ọdún 2005 ni President thabo Mbaki yọ Zuma kúrò ní ipò igbákejì àrẹ nítorí ìwà ìbàjẹ́.[6] Ní ọdún 2006 ni wón fi ẹ̀sùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà.

àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]