Kgalema Motlanthe
Jump to navigation
Jump to search
His Excellency Kgalema Motlanthe | |
---|---|
![]() | |
Igbakeji Aare ile Guusu Afrika | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 9 May 2009 | |
Ààrẹ | Jacob Zuma |
Asíwájú | Baleka Mbete |
Aare ile Guusu Afrika | |
Lórí àga 25 September 2008 – 9 May 2009 | |
Deputy | Baleka Mbete |
Asíwájú | Thabo Mbeki |
Arọ́pò | Jacob Zuma |
Deputy President of the African National Congress | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 18 December 2007 | |
Asíwájú | Jacob Zuma |
Secretary-General of the African National Congress | |
Lórí àga 1997–2007 | |
Asíwájú | Cyril Ramaphosa |
Arọ́pò | Gwede Mantashe |
Personal details | |
Ọjọ́ìbí |
Kgalema Petrus Motlanthe 19 Oṣù Keje 1949 Alexandra, South Africa |
Ẹgbẹ́ olóṣèlu | African National Congress |
Spouse(s) | Mapula Motlanthe |
Kgalema Petrus Motlanthe (pìpè [ˈkx͡ɑ.lɪ.mɑ mʊ.ˈtɬ͡’ɑ.n.tʰɛ])[1] (bibi 19 July 1949) je oloselu ara ile Guusu Afrika to di Aare ile Guusu Afrika larin 25 September 2008 ati 9 May 2009, lati se imupari akoko keji Thabo Mbeki ti o siwo ise gege bi Aare.[2]
Lowolowo Motlanthe ni Igbakeji Aare si Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ Recording of him taking the oath of office http://news.bbc.co.uk/2/hi/in_depth/7636151.stm
- ↑ "Zuma sworn in as SA’s fourth democratic President". SABC. 2009-05-09. http://196.35.74.238/portal/site/SABCNews/menuitem.5c4f8fe7ee929f602ea12ea1674daeb9/?vgnextoid=82f7f279f6421210VgnVCM10000077d4ea9bRCRD&vgnextfmt=default&channelPath=home. Retrieved 2009-05-09.
|