Jean-Marie Doré

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jean-Marie Doré
Prime Minister of Guinea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
26 January 2010
ÀàrẹSékouba Konaté (Acting)
AsíwájúKabiné Komara
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1939
Guinée Forestière, Guinea
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnion for the Progress of Guinea

Jean-Marie Doré (ojoibi 1939?[1]) je oloselu ara orile-ede Guinea. O je Aare egbe oloselu Union for the Progress of Guinea (UPG) ati Alakoso Agba ile Guinea lati January 2010.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Saliou Samb, "Possible candidates for Guinean PM job", Reuters, 14 January 2010.