Sékou Touré
Ahmed Sékou Touré | |
---|---|
President Ahmed Sékou Touré of the Republic of Guinea arrives at Andrews Air Force Base in Maryland during a visit to Washington DC. (June 1982) | |
1st President of Guinea | |
In office October 2, 1958 – March 26, 1984 | |
Asíwájú | None (position first established) |
Arọ́pò | Louis Lansana Beavogui |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Faranah, French Guinea | Oṣù Kínní 9, 1922
Aláìsí | March 26, 1984 Cleveland, Ohio, United States | (ọmọ ọdún 62)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Guinean |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party of Guinea |
Ahmed Sékou Touré (bamiran Ahmen Seku Ture) (January 9, 1922 – March 26, 1984) je asiwaju oloselu ara Afrika ati Aare orile-ede Guinea lati odun 1958 titi di ojo iku re ni odun 1984. Touré je enikan pataki larin awon asetomoorile-ede Guinea ti won kopa ninu igbominira orile-ede na lowo France.
Igba ewe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sékou Touré je bibi ni January 9, 1922 sinu ebi awon eniyan Mandinka ni Faranah, French Guinea, lasiko tibe je ohun alamusin ile Fransi. He was an aristocratic member of the Mandinka ethnic group[1] and was the great-grandson of the famous Samory Touré,[2], who had resisted French rule until his capture.
Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2021, ni akoko ayẹyẹ 50th ti ipakupa Oṣu Kẹwa ọdun 1971, awọn ibatan ti 70 Guineans ti o pa labẹ ijọba Sékou Touré beere lọwọ Alakoso Mamady Doumbouya fun isọdọtun ati isinku ti o ni ọla fun awọn olufaragba naa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ RADIO-KANKAN: La premiere radio internet de Guinée-Conakry: GUINEE: RADIO-KANKAN
- ↑ Webster, James & Boahen, Adu (1980), The Revolutionary Years; West Africa since 1800, p. 324.