Kwame Ture
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Stokely Carmichael)
Kwame Ture | |
---|---|
4th Chairman of the Student Nonviolent Coordinating Committee | |
In office May 1966 – June 1967 | |
Asíwájú | John Lewis |
Arọ́pò | H. Rap Brown |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Stokely Standiford Churchill Carmichael Oṣù Kẹfà 29, 1941 Port of Spain, Trinidad and Tobago |
Aláìsí | November 15, 1998 Conakry, Guinea | (ọmọ ọdún 57)
(Àwọn) olólùfẹ́ | Miriam Makeba (m. 1968; div. 1973) Marlyatou Barry (divorced) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Education | Bronx High School of Science (1960) |
Alma mater | Howard University (B.A., Philosophy, 1964) |
Kwame Ture ( /ˈkwɑːmeɪ ˈtʊəreɪ/; orúkọ àbísọ Stokely Standiford Churchill Carmichael, June 29, 1941 – November 15, 1998) jẹ́ alákitiyan ará Trínídàd tò kópa nínú ìrìnkankan àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti nínú Pan-African movement|ìrìnkankan Ìṣe Pan-Áfríkà lágbàáyé. Wọ́n bíi ní orílẹ̀-èdè Trinidad, sùgbọ́n ó dàgbà ní Amẹ́ríkà láti ìgbà ọmọ ọdún 11, ó sì di alákitiyan nígbà tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní Yunifásítì Howard.