Coretta Scott King

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Coretta Scott King
Coretta Scott King.jpg
King at the 30th anniversary of the March on Washington, 1993
Ọjọ́ìbí Coretta Scott
(1927-04-27)Oṣù Kẹrin 27, 1927
Marion, Alabama, U.S.
Aláìsí January 30, 2006(2006-01-30) (ọmọ ọdún 78)
Rosarito Beach, Mexico
Resting place King Center for Nonviolent Social Change
(Atlanta, Georgia)
Ẹ̀kọ́ Antioch College (BA)
New England Conservatory of Music (BM)
Iṣẹ́ Civil rights, women's rights, gay rights, human rights, and equal rights activist; author
Spouse(s)
Martin Luther King Jr.
(m. 1953; died 1968)
Children Yolanda King
Martin Luther King III
Dexter Scott King
Bernice King
Relatives Yolanda Renee King (granddaughter)
Alveda King (niece)
Awards Gandhi Peace Prize
Coretta Scott King Award for Authors

Coretta Scott King (April 27, 1927 – January 30, 2006) jẹ́ olùkọ̀wé, alákitiyan, aṣíwájú fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà, àtí ìyàwó Martin Luther King Jr.. Ó ṣakitiyan fún ìbáradọ́gba àwọn ọmọ African-American, ó ṣe aṣíwájú fún Civil Rights Movement ní 1960s. King tún jẹ́ akọrin tó lo orin nínú iṣẹ́ rẹ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú. King bá ọkọ rẹ̀ pàdé nkgbà tí wọ́n jọ wà ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì ní Boston.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]