A. Philip Randolph
Ìrísí
Philip Randolph | |
---|---|
A. Philip Randolph in 1963 | |
Ọjọ́ìbí | Crescent City, Florida | Oṣù Kẹrin 15, 1889
Aláìsí | May 16, 1979 New York City | (ọmọ ọdún 90)
Asa Philip Randolph (April 15, 1889 – May 16, 1979) jẹ́ alákitiyan ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ asíwájú nínú ìrìnkánkán ẹ̀tọ́ aráàlú àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, ìrìnkánkán ọ̀ṣìṣẹ́ Amẹ́ríkà àti àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú sósíálístì.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |