Moussa Camara
Appearance
(Àtúnjúwe láti Moussa Dadis Camara)
Moussa Dadis Camara | |
---|---|
President of Guinea | |
In office 24 December 2008 – 3 December 2009 | |
Alákóso Àgbà | Kabiné Komara |
Asíwájú | Lansana Conté |
Arọ́pò | Sékouba Konaté (Acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1964 Koure, Guinea |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Council for Democracy and Development |
Àwọn ọmọ | 4 |
Alma mater | University of Conakry |
Profession | Soldier |
Website | Official website |
Moussa Dadis Camara (ojoibi 1964) je oga ologun tele ni Ise Ologun ile Guinea to di Aare orile-ede Guinea fun National Council for Democracy and Development (Conseil National de la Démocratie et du Développement, CNDD), eyi to fi tipatipa gba ijoba ni 23 December 2008 leyin iku Aare Lansana Conté. O ti kuro lori aga lati igba igbidanwo ipani to sele si ni 3 December 2009. Ni Oṣu Keje Ọjọ 31, Ọdun 2024, Moussa Dadis Camara jẹbi “awọn iwa-ipa si ẹda eniyan” ninu awọn ipakupa ti o waye ni ọdun 2009, ati pe o dajọ ọdun ogun ọdun sẹwọn.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Qui est Moussa Dadis Camara, le nouveau president de la Guinee?" Archived 2012-02-16 at the Wayback Machine., Guineenews, 26 December 2008 (Faransé).
- ↑ [https://www.rfi.fr/fr/afrique/20240731-proc%C3%A8s-du-massacre-de-2009-en-guin%C3%A9e-moussa-dadis-camara-d%C3%A9clar%C3%A9-coupable-de-crimes-contre-l-humanit%C3%A9 "Afrique Procès du massacre de 2009 en Guinée: Moussa Dadis Camara condamné à 20 ans de prison pour crimes contre l’humanité"]. Radio France International. 2024-07-31. https://www.rfi.fr/fr/afrique/20240731-proc%C3%A8s-du-massacre-de-2009-en-guin%C3%A9e-moussa-dadis-camara-d%C3%A9clar%C3%A9-coupable-de-crimes-contre-l-humanit%C3%A9. Retrieved 2024-07-31.