Moussa Camara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Moussa Dadis Camara
Dadis Camara portrait.JPG
President of Guinea
Lórí àga
24 December 2008 – 3 December 2009
Aṣàkóso Àgbà Kabiné Komara
Asíwájú Lansana Conté
Arọ́pò Sékouba Konaté (Acting)
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 1964
Koure, Guinea
Ẹgbẹ́ olóṣèlú National Council for Democracy and Development
Àwọn ọmọ 4
Alma mater University of Conakry
Profession Soldier
Ẹ̀sìn Christianity[1]
Website Official website

Moussa Dadis Camara (ojoibi 1964) je oga ologun tele ni Ise Ologun ile Guinea to di Aare orile-ede Guinea fun National Council for Democracy and Development (Conseil National de la Démocratie et du Développement, CNDD), eyi to fi tipatipa gba ijoba ni 23 December 2008 leyin iku Aare Lansana Conté. O ti kuro lori aga lati igba igbidanwo ipani to sele si ni 3 December 2009.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]