Louis Lansana Beavogui
Ìrísí
Louis Lansana Beavogui (28 December 1923 – 19 August 1984) je oloselu ara Guinea. O je Alakoso Agba ile Guinea lati 1972 de 1984 beesini o je Aare igbadie ni 1984.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |