Frantz Fanon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Frantz Fanon
Ọjọ́ ìbí20 July 1925
Fort-de-France (Martinique, France)
Ọjọ́ aláìsí6 December 1961
Bethesda, Maryland
SpouseJosie Fanon
ChildrenOlivier Fanon Mireille Fanon-Mendès
Frantz Fanon (1959)

Frantz Fanon (July 20, 1925 – December 6, 1961) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Faransé oníwọsàn ààrùn ọpọlọ, amoye, olujidide àti oǹkọ̀wé tí àwọn ìwé rẹ̀ dá lórí àwọn Ẹ̀kọ́ ìgbà eyin imusin, critical theory ati Marxism.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]