Jorge Luis Borges
Appearance
Jorge Luis Borges | |
---|---|
Borges in 1951, by Grete Stern | |
Iṣẹ́ | Writer, poet, critic, librarian |
Èdè | Spanish |
Jorge Francisco Isidoro Luis Borges Acevedo (August 24, 1899 – June 14, 1986), to gbajumo lasan bi Jorge Luis Borges (Pípè: [ˈxorxe ˈlwis ˈborxes]), je omo ile Argentina to je olukowe, alaroko, ati akoewi to je bibi ni Buenos Aires.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |