Jump to content

João Lourenço

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
João Lourenço

Lourenço in 2018
4th President of Angola
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
26 September 2017
Vice PresidentBornito de Sousa
AsíwájúJosé Eduardo dos Santos
Minister of National Defense
In office
22 April 2014 – 26 September 2017
ÀàrẹJosé Eduardo dos Santos
AsíwájúCândido Pereira dos Santos
Van-Dúnem
Arọ́pòSalviano de Jesus Sequeira
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kẹta 1954 (1954-03-05) (ọmọ ọdún 70)
Lobito, Portuguese Angola
(now Angola)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúMPLA (1974–present)
(Àwọn) olólùfẹ́Ana Afonso Dias
Àwọn ọmọ6
Alma materIndustrial Institute of Luanda
Lenin Superior Academy
Nickname(s)JLo[1]

João Manuel Gonçalves Lourenço, GColIH (pípè:Jao Manuel Gonsafes Lourenso ọjọ́ìbí 5 March 1954) ni olóṣèlú ará Angola tó ti wà nípò bíi Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà láti 26 September 2017.[2] Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, ó jẹ́ Alákóso Ètò Àbò ilẹ̀ Àngólà láti 2014 dé 2017. Ní September 2018 ó di Alága ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Movement for the Liberation of Angola (MPLA), tíí ṣe ẹgbẹ́ olóṣèlú tó wà lórí ìjọba.