Portuguese Angola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Província de Angola
Province of Angola
Colony of the Portuguese Empire (1575–1951)
Overseas Province of Portugal (1951–1972)
State of the Portuguese Empire (1972–1975)

 

 

1575–1975
Flag Coat of arms
Anthem
"Hymno Patriótico" (1808–34)
Patriotic Anthem

"Hino da Carta" (1834–1910)
Hymn of the Charter

"A Portuguesa" (1910–75)
The Portuguese
Location of Angola
Portuguese West Africa in 1905–1975
Capital Luanda
Language(s) Portuguese (official)
Umbundu, Kimbundu, Kikongo, Chokwe
Religion Roman Catholicism[1]
Protestantism
Traditional religions
Government Colonial government
Head of State
 - 1575–78 King Sebastian I of Portugal
 - 1974–75 President Francisco da Costa Gomes
Governor General
 - 1575–1589 Paulo Dias de Novais[2]
 - 1975 Leonel Alexandre Gomes Cardoso
Historical era Imperialism
 - Establishment of Luanda 1575
 - Fall of the Portuguese Empire 11 November, 1975
Currency Portuguese real (1575-1911)
Portuguese escudo (1911–14)
Angolan escudo (1914–28; 1958–77)
Angolan angolar (1926–58)
Ní òní ó jẹ́ apá Angola
Warning: Value not specified for "continent"

Portuguese Angola jẹ́ o Angola nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ ìjọba Portuguese ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn Áfríkà. Orúkọ ko rẹ̀ títí di ọdún 1951 ni Portuguese West Africa (tàbí State of West Africa).

Ní ṣẹ́ntúrì ogún ni Ìjàdù fún Áfríkà ni àwọn alágbara ní Europe tó kó gbogbo ìlú náà lẹ́rú.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Portuguese jọba lórí Angola láàrin ìgbà tí Diogo Cão jọba ní ọdún 1484[3] títí ti osù kọkànlá ọdún 1975. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ǹkan ni ó ṣẹlẹ̀ láàrin ọgọ́rùn-ún márùn-ún ọdún yìí.

Ìgbà tí wọ́n ko wọn lẹ́rú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Queen Nzinga níbi tí ó ti ń bá gómìnà Portugal sọ̀rọ̀ ní Luanda, ní ọdún 1657

Angola ò tí sí nígbà tí Diogo Cão àti àwọn tó kù rẹ̀ dé Ìjọba Kongo ní ṣẹ́ńtúrì kẹ̀ẹ́dógún. Ibi tí Angola wà lọ́wọ́ lọ́wọ́ jẹ́ ibi tí oríṣiríṣi àwọn ẹ̀yà àti ènìyàn wà nígbà náà. Ète àwọn ará Portugal nígbà náà ni láti kó ẹrú. Wọ́n sì ní ìbásepọ̀ tó da pẹ̀lú àwọn adarí àti òtòkùlú ìjọba Kongo, wọ́n fi ẹ̀sìn Kristẹ́nì lọ̀ wọ́n, wọ́n sì kọ́ wọn ní èdè Portuguese, wọ́n tún jé kí wọn jẹ àwọn ànfàní ọkọ òwò ẹrú tí wọ́n ń ṣe.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. James, Martin W. (2004). Historical Dictionary of Angola. Scarecrow Press. p. 140. ISBN 9780810865600. https://books.google.com/books?id=JTSoqGzOPXsC&q=angola+state+religion&pg=PA140. 
  2. as Captain-Governor
  3. Chisholm 1911.