Jump to content

Jumoke Akindele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jumoke Akindele
In office
27 May 2014 – 20 March 2017(kòwẹ́ fipòsílẹ̀)[1]
ConstituencyÒndó, Okitipupa Constituency II
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÒndó, Nàìjíríà
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
ResidenceOkitipupa
OccupationAgbẹjọ́rò

Jumoke Akindele jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì tún jẹ́ obìnrin Olórí àkọ́kọ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ondo.[2][3][4]

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Jumoke Akindele ni wọ́n bí ni Okitipupa, ilu kan ni Ipinle Ondo ni guusu ìwò òòrùn Nàìjíríà. O lọ íle ẹ̀kọ́ alakobere re ni St John's Primary School ni Okitipupa ki o to lo si St Louis Girls Secondary School, Ondo nibi ti o ti gba Iwe eri Ile-iwe West Africa(WAEC) ni odun 1981. Jumoke gba oye ẹyẹ ninu imo ofin lati Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé-Ifẹ̀ o si se ise asofin fun opolopo odun ki o to di oselu lodun 2006.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Olowookere, Dipo (March 20, 2017). "Jumoke Akindele Resigns as Ondo Speaker - Business Post Nigeria". Business Post Nigeria. Retrieved May 22, 2022. 
  2. "Ondo State House of Assembly Speaker, Mrs. Jumoke Akindele resigns". TVC News. March 21, 2017. Retrieved May 22, 2022. 
  3. "Why women are lagging behind in politics- Ondo Speaker". The Nation Newspaper. June 8, 2014. Retrieved May 22, 2022. 
  4. Yakubu, Temitope (July 28, 2019). "Ondo ex-speaker: Akeredolu treating state lawmakers like errand boys". TheCable. Retrieved May 22, 2022.