Jumoke Odetola
Ìrísí
Olajumoke Odetola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Olajumoke Odetola 16 Oṣù Kẹ̀wá 1983 Eko,Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ajayi Crowther University |
Iṣẹ́ | Actress | Model | Producer |
Jumoke Odetola jẹ́ òṣèrébìnrin órílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2][3][4]
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Jumoke Odetola lọ́jọ́ kerindinlógún oṣù Kewa ọdún 1983 si ilu Èkó. Jumoke jẹ́ abikeyin ninu ọmọ meje tí àwọn òbí rẹ̀ bí.[5] Ó lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ ABATI Nur/Pry School ní Ìpínlẹ̀ Èkó,ti o si lo ile -iwe girama ti o wa ni Abeokuta ( Abeokuta Grammar School)Ó lọ sí Yunifásítì Ajayi Crowther ( Ajayi Crowther University).
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bada, Gbenga (April 9, 2016). "'Boyfriends are distractions,' AMVCA's best indigenous act says". Pulse Nigeria. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ "Jumoke Odetola bags 100 Most Influential Young Leaders in Nigeria award". Tribune Online. April 2, 2022. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ Olawale, Gabriel (February 20, 2022). "Jumoke Odetola bags Ambassadorial deal with Success Foods". Vanguard News. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ "Actress Jumoke Odetola Causes A Stir As She Shares Loved-up Photos Of Herself With Popular Actor". Global Times Nigeria. February 22, 2022. Archived from the original on February 22, 2022. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ "My father never wanted me to become an actress - Jumoke Odetola". Tribune Online. March 5, 2021. Retrieved May 21, 2022.