Jump to content

Kìnìún

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kìnìún, Ọba àwọn ẹranko
Lion
Temporal range: Pleistocene–Present
Akọ kìnìún ní Okonjima, Namibia
Abo kìnìún ní Okonjima
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Ajẹran
Suborder: Ajọ-ológìnní
Ìdílé: Ẹ̀dá-ológìnní
Subfamily: Pantherinae
Ìbátan: Panthera
Irú:
P. leo[1]
Ìfúnlórúkọ méjì
Panthera leo[1]
Subspecies
P. l. leo
P. l. melanochaita
daggerP. l. sinhaleyus
Historical and present distribution of lion in Africa, Asia and Europe
igbo
igbó pèlú omi ti o subu ati àwọn igi
Kiniún àgba ati omo re, won ti pa ẹranko ati nisinsin, won jẹun

Kìnìún, Ọba àwọn ẹranko (Panthera leo)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon kiniún wa awon ẹranko pelu agbara ti o tobi gan! Awa n pe awon Kiniun, «Oba awon ẹranko» ṣùgbọ́n o le béèrè, «kini idi awa n pe won «Ọba awon ẹranko» o ti béèrè dáradára, idi ti awa n pe won «Ọba awon ẹranko» je nitori pé won je «Ọba awon ẹranko» Awon kìnìún, won le pariwo pẹ̀lú ariwo ti ó pọ̀ gan ju gbogbo ẹranko ni igbó. Ti won ba pariwo, gbogbo ẹranko won ma sáré fun igbesi ayé won. Nitori, ko si ẹranko ni igbó ti o le se jagun pẹ̀lú kìnìún, ti won ba gbiyanju, won ma padanu gidigan. E ma duro pẹ̀lú awon kiniun. Ti awa maa fi fi òṣù awon kìnìún, òṣù won ma ju poun ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta.

Awon kiniun je àwọ̀ igi, won ni àwọn ehin ati ara ti ni agbára, won le parun ati fa silẹ awon igi ati won le pa orisirisi ẹranko ati se awon ohun ńlá.[4] ati awon isé agbára.

Awon kiniún je ààmi ti agbára, fun awon kristeni, awa n pe Jesu Kristi "kiniún ti eya Judah." (Ìfìhan 5:5)[5]

Àwọn kiniún won gbé ati duro lapapo pèlú awon miiràn kiniún, ni akojọpọ ti meedogun.[6] Àwon akojọpọ ti kiniún, won le ni meta si ẹranko ogóji (3-40). Àwọn kiniún, won nilo lati dẹ, àwọn ikogun, kó àwọn omodé won, ati dabòbò ilẹ won. Àwọn abo-kiniún, won ma de àwọn ikogun ati won maa kó omodé won. Ni asiko ti o po, àwon abo-kiniun ni akojọpọ je tan, won wa arabirin. [6]

Ni àwọn àkókò ti o po àwón abo-kiniún won ma bi ọmọ won ni àkókò kanna. Àwọn, orisirisi abo-kiniún, won le toju ara ti miiràn omo. Àwọn akojọpọ, ni asiko ti o po, won ko ma ni kiniún àgba ti akọ ti poju méji.[6]

Àwon abo-kiniún, won ma dúró pèlú akojọpọ won fun gbogbo igbesi ayé won sùgbón àwọn kiniún ako, won ma dúró fun odun nikan méji si mẹrin (2-4). Nigba ti odun méji si odun mẹrin (2-4) ti pari, won ma jadé tabi àwọn kiniún miiràn ti o ma gbé akoso lori akojọpọ, won ma ran won jadé. [6] Nigba ti kiniun akọ je oga ti akojọpọ, o ma pa gbogbo omodé ti kiniún miirán nitori pé o fe pé gbogbo omodé o ma ni jiini kanna pèlú óun. Isé akókó ti àwọn kiniun akọ je lati dabòbò àwọn ile ti akojọpọ. Ni ọjọ dede, àwọn kiniún won ma bu ramuramu ni asalé. Won le bu ramuramu pèlú ariwo ti o tobi gan. E le gbó ti e ba je jijina ti po ju kilomita méjo (8). [6]

Ariwo, o ma se beru àwọn ẹranko ti o fe yọju tabi wà laipè ati lati mu awon kiniún ninu akojopo lati kojo.[6]

Awon kiniún abo, won ma dẹ, súgbón, won ko dẹ dada. Won ma dẹ ni akojopo ti kiniún méji tabi mẹta, (2-3) ati lapapo, won ma duro, won ma yi kakiri, ati won ma pa ikógun won. Ti o ba kiniún ti ko je ninu akojopo won fe wole, àwọn kiniún, won ma se jagun pèlú won. Àwon kiniún ako won ma jẹ ni akókó, leyin naa àwon kiniún abo won ma jẹ, ati àwon omodé won ma jẹ ti ikẹhin.[6]

Nitori pé àwọn kiniún, won tobi gan, ati won ni agbara nla, ati won ni ebun lati pa àwọn ẹranko miiràn, awa n pè won "Ológbò Nla" ati o je kanna fun àwọn kiniun ti òkè, ekùn, amotekun, cougar, ati lynx. [6]

Àwọn kiniún, won le fo ga, won le fo mewaa mita ni ofurufu.[7]

Nibo ni awon Kiniun won n gbé?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Won le gbé ni orisirisi ile, won n gbé ni igbó, erè ( ira pètèpété ), ati koriko igbẹ. [8]

Orilẹ-ede wo ni awon Kiniun won n gbé?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gbogbo kiniun, won n gbé ninu Áfíríkà. [9]

Kini awon Kiniun, won jẹ?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Won je awon abilà, ẹfọ̀n, ati awon ẹyẹ. Àwọn kiniun won le jẹ awon orisirisi ohun.

Kini iyara ti awon kiniun?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon kiniun le sáré kiakia pèlú iyara ti kilomita ọgọrin ni wákàti ọkàn (80km/w) . Iyara yii, ó ju iyara ti àwọn èniyàn ni gbogbo ayé lọ. Usain Bolt je okunrin kiakia julo ti gbogbo ayé, èniyàn dudu, o le sáré pèlú iyara ti merinlelọgọji kilomita ni wákàti ọkan (39km/w). Awon kiniún le sáré igbà méji kiakia ju èniyàn kiakia julo ti gbogbo ayé lọ. bẹẹ ni, awon kìnìún, won le sáré kiakia gidigan! Ti e ba wò kiniun, e ma duro pèlú òun![10]

Àwọn kiniun won le bu ramùrámù ati won le pariwo pèlú ariwo ati igbe ti o tobi gan!

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ti won ba pariwo ati mu ramùrámù, won ma pariwo ati e ma gbó won pàápàá ti e ba je jina bóyá jijina ti méjo kilomita [11]

Igbó pèlú àwọn ábàgùnkè (àkasọ tabi àtẹ̀gùn)
Akojọpọ kiniún, won je ẹfòn
Kiniún bu ramúràmú, o n pariwo!