Karl Elbs

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Karl Elbs, Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kẹsán Ọdún 1858 ní Alt-Breisach, Baden, Germany – Ọjọ́ kerìnlélógún Oṣù kẹjọ Ọdún 1933) jẹ́ onímọ̀ chemistry ọmọ orílẹ̀ èdè Jamaní. Ohun ní ó ṣèdá  Elbs reaction fún ìṣètò anthracene. Ohun ló tún wà ní idi Elbs persulfate oxidation.

Àwọn ìtọkasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • E. J. Behrman, Bull. Hist. Chem., 30, 19-22(2005).