Jump to content

Kayode Akiolu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kayode Akiolu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress

Kayode Moshood Akiolu je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà o nsójú àgbègbè Lagos Island II ti Ìpínlẹ̀ Eko ni Ile-igbimọ Aṣofin Àgbà kẹwàá [1] [2]

Igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akiolu je ọmọ bibi ìpínlè Eko ni Naijiria. Ọmọ Oba Rilwan Akiolu ni. [3] [4] Lọ́dún 2019, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba àpapọ̀ ní Nàìjíríà, tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Lagos Island II. [5] [6] O je omo egbe All Progressives Congress (APC). [7]