Jump to content

Lateefah Dúrósinmí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lateefah Durosinmi
Ọjọ́ìbíLateefah Moyosore Williams
July 7, 1957
Lagos, Nigeria
IbùgbéIlé-Ifẹ̀
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Writer, Lecturer

Lateefah Moyọ̀sọ́rẹ Dúrósinmí tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1957 jẹ́ olùkọ́ àgbà ti Chemistry àti gíwá tó rí sí ọ̀rọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Obafemi Awolowo University, tí ó wà ní Ilé-Ifẹ̀.[1]

Ìgbésí ayé àti ètò-èkó

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1957 ni a bí Dr. Lateefah sínú ìdílé Williams. Bàbá rẹ̀ ni olóògbé Alhaji Tijani Akanni Williams, ìyá rẹ̀ sì ni Wusamot Abeni Kareem. Ilé-ìwé Patience Modem Girls' Private School ní ìpínlẹ̀ Èkó ni ó ti bẹ̀rẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ó sì lọ sí Girls' Secondary Grammar School ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1974-1976. Ifásitì ti ìlú Ibadan ni ó lọ tó ti ṣe Chemistry. Ní ọdún 1986, ó gboyè Master of Science (M.Sc.) nínú Analytical Chemistry ní Ifásitì kan náà.[2][3] Dr. Lateefah jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ FOMWAN. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "LMD Foundation holds sixth lecture on economic recession -". The Eagle Online (in Èdè Bosnia). 2017-07-04. Retrieved 2020-04-30. 
  2. PeoplePill (1957-07-07). "Lateefah Durosinmi: Nigerian academic - Biography and Life". PeoplePill. Retrieved 2020-04-30. 
  3. "The criterion to discuss deviant ideologies at confab". The Guardian Nigeria News. 2016-02-12. Archived from the original on 2023-10-04. Retrieved 2020-04-30. 
  4. Fomwan Osun State http://fomwanosunstate.org.ng/team-member/3. Retrieved 2020-04-30.  Missing or empty |title= (help)[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]