Lawrence Babatunde Ayeni
Ìrísí
Lawrence Babatunde Ayeni (ojoibi ni ọjọ kokanlelogbon oṣù kẹta ọdún 1961), je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to je ọmọ ile ìgbìmọ̀ asoju-sofin to n ṣoju Atakunmosa East / Atakunmosa West / Ilaorun Ilesa / Ilesa West ni ipinle Osun, labẹ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress (APC), lati 2019 si 2023. [1] [2] [3] [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.vanguardngr.com/2021/07/list-of-house-of-reps-members-and-their-political-parties/
- ↑ https://gazettengr.com/amotekun-adopts-hisbah-tactics-bans-indecent-dressing-poor-use-of-yoruba/
- ↑ https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/ayeni-lawrence-babatunde
- ↑ https://www.constrack.ng/legislator_details?id=285