Jump to content

Lucifer (fíìmù Nàìjíríà 2019)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Lucifer jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2019 tó dá lórí arákùnrin kan tí gbogbo ènìyàn bẹ̀rù ní agbègbè rẹ̀. Tope Adebayo àti Ibrahim Yekini ni olùdarí eré yìí. Orúkọ ìnagije Ibrahim Yekini ni Itele, òun sì ló gbé erẹ́ náa jáde.

Ibrahim Yekini gba àmì-èyẹ òṣèrékùnrin Yorùbá tó dára jù lọ ní BON AWARD ti ọdún 2020 fún fíìmù (Lucifer) yìí.[2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Augoye, Jayne (2020-12-07). "BON Awards: Laura Fidel, Kunle Remi win Best Kiss (Full List of Winners)". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  2. "Ibrahim Yekini beats Lateef Adedimeji, others to best actor award - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  3. Augoye, Jayne (2020-12-02). "2020 BON: Here are 5 nominees for 'Best Kiss' category". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  4. "BON Awards: 'Living In Bondage', 'This Lady Called Life' Win Big". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-06. Retrieved 2022-08-01.