Jump to content

Temitope Solaja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:DMCÀdàkọ:Merge partner

Temitope Solaja
Fáìlì:Temitope Solaja.jpg
Orúkọ mírànStar Girl[1]
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaTai Solarin University of Education
Iṣẹ́Film actress

Temitope SolajaYo-Temitope Solaja.ogg Listen jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, òǹkọ̀tàn àti aṣagbátẹrù fíìmù.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Temitope Solaja jẹ́ ọmọ àkọ́bi àwọn òbí rẹ̀, ìlú SagamuÌpínlẹ̀ Ògùn ló sì ti wá. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ Mass communication láti Tai Solarin University of Education.[2]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2008, Solaja gba iṣẹ́ eré-ṣíṣe àkọ́kọ́ rẹ̀, láti kópa nínú fíìmù Bamitale. Solaja di gbajúmọ̀ òṣèré nígbà tí ó kópa nínú fíìmù tí Sola Akintunde Lagata gbé jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Opolo, ní ọdún 2019.[3] Ní ọdún 2015, ó kọ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Aruga, ó sì gbé e jáde. Àwọn àgbà òṣèré bí i Antar Laniyan, àti Sunkanmi Omobolanle ló kópa nínú fíìmù náà.[4]

Ní ọdún 2017, wọ́n yàn án fún òṣèrébìnrin tó dára jù ní ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2017.[5]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Bamitale
  • Opolo
  • Idemu Ojo kan
  • The Antique
  • Adajo Aiye
  • Kudi Klepto
  • Bella
  • Firepemi
  • Aruga
  • Darasimi
  • Awelewa
  • Orente
  • Juba[6]
  • 77 Bullets[7]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Iṣẹ́ Èsì Ìtọ́ka
2015 Best of Nollywood Awards Best Supporting Actress (Yoruba) Bella Wọ́n pèé [8][9]
2017 Best Actress in a Leading Role (Yoruba) Ashabi Akata Wọ́n pèé
  1. "ICYMI: I can date, marry a fan –Temitope Solaja - Punch Newspapers". Punch Newspapers. February 22, 2020. Retrieved August 3, 2022. 
  2. Oluwafunmilayo, Akinpelu (September 14, 2018). "Actress Temitope Solaja expresses gratitude as she buys new car". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved August 3, 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "4 top up and coming Yoruba actresses: Temitope Solaj". Encomium Magazine. August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022. 
  4. Bada, Gbenga (May 30, 2015). "Watch Antar Laniyan, Biodun Okeowo, others in new Yoruba movie". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022. 
  5. Augoye, Jayne (September 12, 2017). "Omotola Jalade-Ekeinde, Mercy Aigbe, Alexx Ekubo top BON Awards nominee list". Premium Times Nigeria. Retrieved August 3, 2022. 
  6. THISDAYLIVE, Home - (October 16, 2020). "Funmiade Bank-Anthony Explains new Movie – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. Archived from the original on August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022. 
  7. Bada, Gbenga (December 19, 2019). "Mercy Aigbe completes work new film, ‘77 Bullets’". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022. 
  8. Lawal, Fuad (December 14, 2015). "See full list of winners". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022. 
  9. Izuzu, Chibumga (October 26, 2015). "Nse Ikpe-Etim, Stephanie Linus, Hilda Dokubo, Ini Edo, Iyabo Ojo battle for 'Best Actress'". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022.