Jump to content

MV Maersk Andaman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


MV Maersk Andaman (tẹ́lẹ̀tẹ́lè Maersk Alabama) jẹ́ ọkọ̀ ojú omi ẹlẹ́rù ti Maersk Line Limited tí ó wà ní ìmú ṣiṣẹ́ Waterman Steamship Corporation.[1] Ó ní àwọ̀ búlu tí ó fẹ́ mọ́ díẹ̀ pẹ̀lú ìrísí bi ti ọkọ̀  Maersk tókù láì wo tí àsíá ìforúkọsílẹ̀ wọn. Àwọn ajalèlókun jáagbà lẹgbẹ́ Somalia ní ọdún 2009, wọ́ sí mú àwọn atukọ̀ ẹ lati gba owó ìdásilẹ̀. Ìgbìyànjú mẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tò lati já ọkọ̀ náà gbà jásí pàbó lẹ́yìn ọdún náà ní ọdún 2010 àti 2011.[2]

Maersk Alabama kúrò ní Mombasa, Kenya, ní Ọjọ́kanlélógún Oṣù kẹrin ọdún 2009.


China Shipbuilding Corporation, Keelung, Taiwan  kọ́ Alva Maersk ni iye ẹsẹ̀ bàtà ẹgbẹ̀rú méjì àti mẹ́rìnlélógún, ó sì di ìfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1998.[3] Wọ́n wàá lọ sí Denmark. Ní ọdún 2004, wọ́n yí orúkọ Alva Maersk, sí Maersk Alabama[4] wọ́n wàá lọ sí United States, ilé iṣẹ́ tó fi ń ṣisẹ́, Maersk Line, Limited, tí ó wà ní Norfolk, Virginia.[5] Ó ti kópa ní ìṣẹ̀lẹ̀ meje, tí ó sì ń ṣisẹ́ dáradára ní Maersk Line's East Africa 4 service. Ònà tí ó máa ń gbà déédé ni lati  Mombasa, Kenya  Salalah, Oman, si Djibouti, padà sí Mombasa.[5]

Ìdádúró ní ọdún 2004

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2004, wọ́n dá ọkọ̀ yìí dúró ní Kuwait lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣe sábàbí jìbìtì. Gẹ́gẹ́ bí ìwé tí A. P. Moller-Maersk Group fọwọ́sí pẹ̀lú United States District Court for the Southern District of New York ní ọdún 2005, àwọn kan tí wọ́n ń gbé ní Kuwait lu A. P. Moller-Maersk Group ní jìbìtì owó rọ̀gùrọ́gù mílíọnù dọ́là.

Àwọ́n ìtọ́kasi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "2 former Navy SEALs found dead aboard ship at center of ‘Captain Phillips’ saga". Fox News. 2014-02-19. Archived from the original on 2014-06-25. https://web.archive.org/web/20140625195253/http://www.foxnews.com/us/2014/02/19/2-american-contractors-found-dead-aboard-ship-featured-in-movie-captain-philips/. Retrieved 2014-10-23. "Details of the contractors' deaths remain unclear, but they were not on watch and did not die while performing a security operation, Tom Rothrauff, the president of the Trident Group, said. He said an initial assessment of the scene did not suggest any foul play." 
  2. Elizabeth Landau (2014-02-26). "Mystery shrouds 'Captain Phillips' ship deaths". CNN. Archived from the original on 2014-02-26. https://web.archive.org/web/20141008232637/http://www.cnn.com/2014/02/26/world/asia/deaths-captain-phillips-ship/index.html. Retrieved 2014-10-23. "Seychelles police say the autopsy found the cause of death to be "respiratory failure, with suspicion of myocardial infarction (heart attack)." The presence of a syringe and traces of heroin in the cabin have led to a suspicion of drug use, police said." 
  3. Brumfield, Ben (29 April 2014). "Police: Heroin, alcohol at fault in death of security officers on 'Captain Philips' ship". CNN. Archived from the original on 2014-05-02. http://edition.cnn.com/2014/04/29/world/africa/seychelles-maersk-security-deaths/. Retrieved 1 May 2014. "Police said toxicologists in Mauritius found alcohol in the blood of Jeffrey Reynolds, 44, and Mark Kennedy, 43, who both suffered respiratory failure and heart attacks. Foul play was ruled out." 
  4. "Drugs Responsible for Maersk Alabama Deaths". Maritime Executive. 30 April 2014. Archived from the original on 2 May 2014. https://web.archive.org/web/20140502001420/http://www.maritime-executive.com/article/Drugs-Responsible-for-Maersk-Alabama-Deaths-2014-04-30/. Retrieved 1 May 2014. 
  5. "Heart attack and respiratory failure in Maersk deaths". BBC News. 2014-02-24. Archived from the original on 2014-10-23. https://web.archive.org/web/20141023154201/http://www.bbc.com/news/world-us-canada-26331920. "Mark Daniel Kennedy, 43, and Jeffrey Keith Reynolds, 44, were found dead on 18 February as the ship was berthed in Port Victoria, the capital of the Indian Ocean island nation of Seychelles." 
  6. Nicholas Kulish, Ian Urbina, Mark Mazzetti, Jeremy Alford, Christopher Drew, Kristina Rebelo, Susan Beachy, Kitty Bennett (2014-02-26). "Hired to Fight Pirates, but Doomed by Boredom". Victoria, Seychelles: New York Times. p. A1. Archived from the original on 2014-07-10. https://web.archive.org/web/20140710183535/http://www.nytimes.com/2014/02/26/world/africa/hired-to-fight-pirates-but-doomed-by-boredom.html. Retrieved 2014-10-23. "While veterans, especially those returning from war zones, have shown a high prevalence of substance abuse and other risky behaviors, friends, family and acquaintances of the two men said they seemed to have adjusted well to civilian life after years in the military. They were known as much for their zest for life as their hulking physiques."