Jump to content

Manifẹ́stò Kómúnístì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Manifẹ́stò Kómúnístì

Manifẹ́stò Ẹgbẹ́ Kómúnístì (Jẹ́mánì: [Manifest der Kommunistischen Partei] error: {{lang}}: text has italic markup (help); Gẹ̀ẹ́sì: [Manifesto of the Communist Party] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), to unje pipe bi Manifẹ́stò Kómúnístì, je titejade ni February 21, 1848, be sini o je ikan ninu awon iwe kukuru oloselu to nipa julo lagbaye.[1] O je sisakoso latowo Apejo Komunisti o si je kiko latowo awon oludero komunisti Karl Marx ati Friedrich Engels, o selasile idi ati eto Apejo na. O sagbesile ona ija ipele eniyan (nigba atijo ati lowo) ati awon isoro isekapitalisti, kuku isotele bi isekomunisti yio seri ni ojowaju.[2]


  1. Seymour-Smith, Maerin (1998). The 100 Most Influential Books Ever Written: The History of Thought from Ancient Times to Today. Secaucus, NJ: Citadel Press. 
  2. The Great Philosophers, by Jeremy Stangroom and James Garvey, Arcturus 2005/ 2008 ISBN 978-1-84837-018-0, pp160 UKP9.99