Mudashiru Lawal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Mudashiru "Muda" Lawal
Personal information
OrúkọMudashiru Babatunde Lawal
Ọjọ́ ìbí8 June 1954
Ibi ọjọ́ibíAbeokuta, Nigeria
Ọjọ́ aláìsí6 July 1991(1991-07-06) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́aláìsíIbadan, Nigeria
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1975-1984Shooting Stars F.C.
1985-1986Stationery Stores F.C.
1987-1988Abiola Babes
1989-1991Shooting Stars F.C.
National team
1975-1985 Nàìjíríà86(12)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

A bi Mudashiru Babatunde "Muda" Lawal ni odun (8 June 1954 ni Abeokuta o ku ni 6 July 1991 ni ilu Ibadan) . O je agba boolu-arin boolu-elese ara fun orile ede Naijiria. Muda ni eni ti o ti figba kan ri sise atun-oko se nigba ti o sawari ebun gbigbaboolu afesegba,ti o si pinu yaan laayo gege bi ise oojo re. Won gba Mudashiru sinu agbaboolu agba | Super Eagle gege bi eni ti o le di aarin gbungbun mu fun awon akegbe re lori papa ni odun 1975. Bakan naa ni o tun darapo mo egbe agbaboolu ibile ti Shooting Stars F.C. ti o wa ni Ibadan.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]