Muhammad Mustapha Olaroungbe Akanbi
Mohammed Mustapha Olaroungbe Akanbi | |
---|---|
Born | 24 January 1971 |
Died | 24 January 2022 Ilorin, Kwara State | (ọmọ ọdún 51)
Nationality | Nigeria |
Muhammad Mustapha Olaroungbe Akanbi SAN (tí wọ́n bí ní 24 January 1971, tó sì ṣaláìsí ní 20 November 2022) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ẹ̀kọ́ òfin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti igbá kejì olùarí Kwara State University.[1][2] Ó fìgbà kan jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Senior Advocate of Nigeria àti Nigeria Bar Association.
Ìbẹ̀rèpẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Mustapha Akanbi ní ọdún 1971 ní Ile Magaji Kemberi, Awodi, Gambari Quarters, Ilorin East, ní Ìpínlẹ̀ Kwara ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí ìdílé Mustapha Akanbi, tó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba.[3][4][5] Ó gba ìé-ẹ̀rí West African School Certificate láti Federal Government College Okigwe ní ọdún 1989. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ òfin ní Obafemi Awolowo University ní ọdún 1993. Ó gboyè ẹ̀kọ́ ní Nigerian Law School ní ọdún 1995 wọ́n sì pè é sí iṣẹ́, sí ilé-ẹjọ́ ní ọdún kan náà.[4] Ní ọdún 1998, ó gboyè Masters degree nínú ìmọ̀ òfin ní University of Lagos, ní ọdún 1998 ó gboyè Ph.D ní University of London's King's College London, ní United Kingdom ní ọdún 2006.[4][6]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iṣẹ́ ní ìlànà ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mustapha Akanbi bẹ́rẹ́ iṣé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i olùkọ ní faculty of Law ní University of Ilorin, ó sì di ọ̀jọ̀gbọ́n ní ọdún 2012.[7][8] Akanbi fìgbà kan jẹ́ olórí ẹ̀ka Department of Business Law, àti Dean of faculty of Law ní University of Ilorin. Ó sì jẹ́ igbá kejì olùdarí Kwara State University, Malete, títí tí ó fi kú.[9][10]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gé ní onímọ̀ òfin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mustapha Akanbi ṣiṣẹ́ fún orílẹ̀-èdè rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i legal assistant ní legal department ti Central Bank of Nigeria ní Èkó láti ọdún 1995 wọ ọdún 1996. Ní legal firms Gafar & Co, Ilorin àti Wole Bamgbala & Co, Lagos, Olawoyin àti Olawoyin, Lagos àti Ayodele, bákan náà ló ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i òṣìṣé kékeré láti March 1996 títí wọ 1998.[11]
Àwọn ẹgbẹ́ tó darapọ̀ mọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó di ọmọ-ẹgbẹ́ Nigerian Bar Association ní ọdún 1995, àti ọmọ-ẹgbẹ́ Senior Advocate of Nigeria ní ọdún 2018.[4]
Àṣààyàn àwọn ìwé tó kọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Corruption and the challenges of good governance in Nigeria;[12]
- Rule of law in Nigeria;[13]
- The Case For The Integration;[14]
- Customary arbitration in Nigeria: a review of extant judicial parameters and the need for paradigm shift (2015);[15]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Odinkalu, Chidi. "Mustapha Muhammad Akanbi". The Cable.
- ↑ TVCN (2022-11-20). "KWASU VC, Professor Akanbi, dies in Ilorin - Trending News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ Odinkalu, Chidi. "Mustapha Muhammad Akanbi". The Cable.
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 Iwayemi, Zainab (2022-11-21). "Professor Muhammed Akanbi: The academic icon who bagged professorship at 40". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ ODINKALU, CHIDI (2022-11-27). "Tribute to Mohammed Mustapha Olaroungbe Akanbi, January 24, 1971–November 20, 2022". Peoples Gazette (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ Odinkalu, Chidi Anselm. "Mohammed Mustapha Olaroungbe Akanbi (1971-2022)". Premium Times. Retrieved 2023-12-06.
- ↑ Iwayemi, Zainab (2022-11-21). "Professor Muhammed Akanbi: The academic icon who bagged professorship at 40". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ Chioma, Unini (2022-11-20). "KWASU VC, Prof M.M. Akanbi (SAN), Is Dead". TheNigeriaLawyer (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ Odinkalu, Chidi. "Mustapha Muhammad Akanbi". The Cable.
- ↑ ODINKALU, CHIDI (2022-11-27). "Tribute to Mohammed Mustapha Olaroungbe Akanbi, January 24, 1971–November 20, 2022". Peoples Gazette (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-06.
- ↑ "BREAKING: KWASU Vice Chancellor Prof Akanbi dies at 52". Intel Region (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-11-20. Archived from the original on 2023-12-16. Retrieved 2023-12-06.
- ↑ M. M., Akanbi (2004). "Corruption and the challenges of good governance in Nigeria". University of Lagos, Faculty of Social Sciences Journal 6.
- ↑ Mustapha Akanbi, Mohammed; Taiwo Shehu, Ajepe (2012). handle=hein.journals/jawpglob3§ion=2 "Rule of law in Nigeria". Journal of Poly and Globalization 3: 1. https://heinonline.org/hol-cgi-bin/get_pdf.cgi handle=hein.journals/jawpglob3§ion=2.
- ↑ MM, Akanbi (2012). "The Case For The Integration". African Journal of Social Sciences 2 (2): 41–66. https://citeseerx.ist.psu.edu/document?repid=rep1&type=pdf&doi=e37133a34951f4d2873ad44347bde24848b6f50c.
- ↑ M.M., Akanbi; L.A., Abdulrauf; A.A., Daibu (2015). "Customary arbitration in Nigeria: a review of extant judicial parameters and the need for paradigm shift.". Journal of Sustainable Development Law and Policy 6 (1): 199–201. doi:10.4314/jsdlp.v6i1.9. https://www.ajol.info/index.php/jsdlp/article/view/128024.