Jump to content

Musa Isiyaku Ahmed

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Musa Isiyaku Ahmed jẹ́ ọmọ ilé ẹ̀kọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òún ní ìgbákejì àkọkọ́ atí lọ́wọ́lọ́wọ́ tí Ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Agriculture, ZuruÌpínlẹ̀ Kebbi.[1][2][3] Òjògbón Ahmed jẹ́ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Fellow of Veterinary Surgeons Nigeria, Fellow Institute of Human and Natural Resources, Affiliate member Computer Professional Council (CPN), Nigeria Computer Society (NCS) atí ẹgbẹ, Academia in Information Technology Professionals (AITP). Òjògbón Ahmed wá láti Ìpínlẹ̀ Borno ní Nàìjíríà.[4] Ó jẹ́ Òjògbón tẹ́lẹ̀ ní Department of Veterinary, Parasitology àti Entomology ní Yunifásítì ìlú Màídúgùri ní Ìpínlẹ̀ Borno.[5]

  1. IV, Editorial (April 12, 2020). "Prof. Isiyaku appointed VC Kebbi Agric varsity" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  2. "FG Appoints Premier VC for Newly Established University of Agriculture" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). April 10, 2020. 
  3. Labaran, Abubakar (January 7, 2022). "Kachia forum honours Murtala Dabo for service delivery" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  4. "Federal University of Agriculture takes off in Kebbi State | AIT LIVE" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-09. Retrieved 2023-01-11. 
  5. "Federal University of Agriculture takes off in Kebbi State | AIT LIVE" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-09. Retrieved 2023-01-11.