Nọ́mbà àdábáyé
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Nọ́mbà àdábá)
Nínú mathematiki, àwon nọ́mbà àdábáyé, tàbí nọ́mbà àdábá (Natural number) lé jé òkan nínú àkójopò {1, 2, 3,...} (èyun nọ́mbà odidi rere) tàbí òkan nínú àkójopò {0, 1, 2, 3, ...} (èyun gbogbo nọ́mbà tí kí se tí òdì).
A n ló nọ́mbà àdàbà fún kíkà ("Ọsàn mefa lowa ninu apẹ̀rè yị); bé ni á sí tún n ló won fún sisé ètò elésèsè ("Ipo keji ni Bùkọ́lá mu ninu ìdíje sàyẹ̀nsì odun yi").[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Natural Numbers". Brilliant Math & Science Wiki. 2010-01-01. Retrieved 2022-07-28.