Jump to content

NECOM House

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
NECOM House
NECOM Building
Building
TypeCommercial[1]
LocationMarina, Lagos Island, Lagos, Lagos State, Nigeria
Coordinates6°26′46″N 3°23′51″E / 6.4462161°N 3.3975961°E / 6.4462161; 3.3975961Coordinates: 6°26′46″N 3°23′51″E / 6.4462161°N 3.3975961°E / 6.4462161; 3.3975961
Construction
Floor count32[1]
Main contractorCostain Group
Design team
ArchitectNickson Borys & Partners
Structural engineerOscar Faber & Partners in association with Obi Obembe & Associates

NECOM House (tí a mọ̀ sí NITEL Tower tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tí ó sì fìgbà kan jẹ́ NET Building) jẹ́ ilé alájà-púpọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Wọ́n parí kihkọ́ ilé alájà-púpọ̀ náà ní ọdún 1979, ó sì jé olú-ilé NITEL. Kọnkéré ni wọ́n fi kọ́ ilé náà. Ó sì jé ilé tó ga jù lọ ní apá ìwọ̀-oòrùn ilè Africa lásìkò tí wọ́n kọ.

Ilé Necom ti ní ijàm̀bá iná lẹ́ẹ̀mejì, láti ìgbà tí wọ́n ti kọ́ ọ. Àkọ́kọ́ ní ọdún 1983[2] èyí sì fa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsòfò dúkìá, èkejì sì wáyé ní ọdún 2015 tí ó kan orí-àjà ilé náà.

Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]