Nọ́mbà alòdì àti nọ́mbà adájú
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Negative number)
Jije alòdì tabi àìlòdì je ohun ini nomba kan to je gidi, tabi ara omoakojopo awon nomba gidi bi awon nomba onipin ati odidi. Nomba alodi ni awon nomba tiwonkere ju òdo lo fun apere -, -1.44, -1. Nomba adaju (fun apere nomba gidi todaju, nomba onipin todaju, nomba odidi todaju) je nomba topoju odo lo, fun apere , 1.44, 1. Òdo fun ra re ki se odi tabi odaju. Àwon nomba ailoodi je awon nomba adaju ati odo. Awon nomba aidaju je nomba alodi ati odo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |